Ibanuje ati ogbe okan lo je nigba ti irohin wipe awon agbebon kan ti yin'bon pa Alhaji Fatai Yusuf eni ti gbogbo eyan mo si Oko Oloyun ni nkan bi ago merin-abo ni agbegbe Eruwa-Igboora ni ijoba ipinle Ibarapa.
Gege bi atejade ti awon ti oro na se oju won so, won ni nibiti o tin pada lo ile ni awon agbebon na ti da ibon bole, ti arakunrin na si gbemi mi.
Awon gbofinro ti wa bere iwadi to peye lori oro na.Wayi, won ti gbe oku arakunrin na lo si ilewosan ti ijoba to wa ni agbegbe Igbo-Ora General Hospital
Comments
Post a Comment