Akekobirin omo ile eko Usman Danfodio University, Sokoto (UDUS) ti oruko re n'je Hauwa Kana ti awon ajinigbe ji gbe ni ipinle Nassarawa ni awon ajinigbe na ti tu sile.
Opoplopo awon ore ati molebi arabirin na lo tin dupe lowo Olorun fun anfani ati ore ofe ti won rigba nipa wipe awon ajinigbe na tu arabirin na sile layo ati alafia.
Awon agbofinro wayi o wa da owo iwadi won duro, won fi won lokan bale wipe owo palaba awon ajinigbe na o segi lai pe.
Comments
Post a Comment