Ijoba orilede Iran ti pese ogorin millionu dollar fun enikeni to ba le be ori Donald Trump fun Ogun



Nibi eto isinku ogagun Qasem Sulemani eniti awon omo ologun orilede America yin ado oloro pa ni ilu Bagdad pelu ase Donald Trump. Awon ton se amojuto eto isinku na ninu waasi ati ilaniloye ti won gbe kale ti wa gbe owo toto ogorin millionu dollar kale gun enikeni to ba le pa Aare orilede America Donald Trump.

Aare orilede Iran nigba ton ba awon akoroyin soro fi idi re mule wipe ara o ni ro okun-ro adiye fun Donald Trump ati gbogbo awon omo orilede America paapa julo ti owo ba file bawon.

Awon adari orilede bi UK, Russia ati bebe lo ti wa kilo fun orilede Iran lati ma gba esu laye, ki won si ma da ogun sile nitoripe ibere ogun la mo, ko si eni to mo opin re.

Comments