Idunu nla lo je fun gbogbo omo bibi iran Yoruba loni nigba ti Alafin Oyo Oba Lamidi Adeyemi, Iku baba Yeye fi gbajugbaja olorin fuji, Kwam 1 Ayinde Mashal je oye mayegun ile Yoruba ni Aafin re loni. Eyi waye latari wipe oni lo pe odun mokandiladota ti Kabiyesi gun ori apere gege bi Alafin Oyo.
Opolopo awon eyan jankan-jankan lo wa peju sibi ayeye ifinijoye na, ti won si ki ku orire.
Awon Aworan nibi ayeye na ni yi;
Comments
Post a Comment