O ma se o! Iya oserebirin Adora Ukoh ti papoda

Oserebirin Adora Ukoh loni lo fi ibanuje re han lori ero ayelujara instagram lori iku iya re arabirin AGBALAKAIBIE.

O se atejade kan ni ede Yoruba lati ki ologbe na wipe odigba o se.

Atejade na ni yi ni ede geesi;

What A DARK DAY!!!!
BUT I GIVE GOD GLORY
MY MUM PASSED ON TODAY. Keep resting on AGBALAKAIBIE
YOU GAVE A GOOD FIGHT
BUT GOD KNOWS BEST.

________________________
FAREWELL MOTHER
FAREWELL.
WE LOVE YOU FOR ALL YOU DID FOR US
ADIEU MUMMY
KEEP RESTING.

Adura wa ni wipe ki ojo jina sira, ki olorun si te ologbe na si afefe ire. Amin.

Comments