'Ogun asotele ki pa aro to ba gbon'. Ijoba America ti kilo fun awon omobibi America lati ko eru won kuro ni orilede Iran


Leyin igba ti awon omo ologun orilede America labe idari Aare Donald Trump ti yin ado oloro lu oga ologun orilede Iran Qasem Soleimani ti eleyi to se iku pa ni nkan bi ojo melo kan seyin.

Ijoba orilede America ti wa se ikilo fun awon omo bibi orilede America to wa ni orilede Iran,  Dubai, Abu Dhabi ati Israel nitoripe awon yoruba so wipe on bo, on bo, awon lan de de. Ogun agbaye eleketa tin rugbo bo, eni to ba si ni emi ara re lo, ninu awon bibi orilede America, gbodo tete pada wale, ki ogun na to bere.

Comments