Oni ni ayeye odun keje igbeyawo oserekunrin Deyemi Okanlawon ati Iyawo re Damilola


Gbajugbaja oserekunrin Deyemi Okanlawon ati ololure re Damilola ninu atejade kan ti won se loni fi idunu won han lati se ayeye ojo igbeyawo won ofun keje.

Ninu atejade na ti won se lori ero ayelujara instagram, won dupe lowo Olorun, won si ki ara won ku aduroti ati afehiti lojojumo.

Atejade na ni yi ni ede geesi;




Comments