Aisan LASSA ti gba emi awon marun ni ipinle Kogi


Ibanuje nla lo je nigba ti irohin iku awon marun ninu awon mesan ti iwadi ti fi idi re mule wipe won ni aisan LASSA ni ipinle Kogi to wa leti.

Gege bi atejade ti ajo ton mojuto eto ilera ni ipinle na se, won fi han wipe okere tan, awon eyan metalelogbon ni won ti fi idi re mule wipe won ti fi ara kasa aisan na, ti awon metadinlogun si ti ri itoju to peye.

Ninu awon merin to ku yi, meji ninu won wa lati ijoba ipinle Ibaji, ti awon meti si wa lati ijoba ipinle Idah,Okehi ati Igalamela. Awon dokita ti wa gba awon eyan loye wipe ki won kiyesara, ki won si ma sora pelu awon ounje won. 

Comments