Arakunrin kan ti dagbere fa'ye, leyin igba to gbe olosho lo si ile itura +18



Owo palaba arakunrin kan segi nigba ti o dagbere fun aye wipe o digba o se leyin igba to ba arabirin asewo kan ni ajosepo ni ile itura kan to wa ni ilu Calabar.

Gege bi iwadi ati atejade to ti enu odomode birin oni nabi na jade si owo awon agbofinro, arabirin na so wipe, leyin igba ti arakunrin na ba oun ni ajosepo ni nkan bi ago marun, ni o pada si oju orun, ti ko si ji mo. Nigba ti won bi wipe bawo ni o se mo wipe arakunrin na ti ku, o so wipe nigba ti ile mo, ti oun ji arakunrin na, ti ko daun , ni oun ya tete ke gbajari, ti oun si tete fi to awon osise ile itura na leti wipe kayefi nla ti sele.

Awon agbofinro ti wa gbe oku arakunrin na lo si ile igbokusi, won si ti mu odomode birin olosho na lo si ago olopa fun iwadi to peye.

Comments