Asoju orilede Saudi Arabia si Nigeria ogbeni Adnan Bostaji ti ku

Arakunrin Adnan Bosteni, eni to je asoju orilede Saudi Arabia si orilede Nigeria ni iroyin fi to wa leti wipe o ti dagbere faye nigbati o sun orun ranpe kan ni ojo kerin osu keji odun ta wa ninu re yi.

Iroyin na ni awon osise ile ise ton mojuto gbogbo isele ton sele ni orilede Saudi Arabia fi mule ninu atejade ranpe kan ti won se ni ede geesi.

Atejade na ni yi;

"With the deepest sense of sadness and complete submission to the will of Allah, Royal Embassy announces the passing away of His Excellency, the Ambassador of the Kingdom of Saudi Arabia to Nigeria, Mr. Adnan Mahmoud Bostaji. May his blessed soul rest in peace.”

Adura wa ni wipe ki Olorun te ologbe na si afefe ire. Amin.

Comments