Awon akeko ile eko giga LAUTECH gbe ebo kankan ton ka igun laya si enu ona Oluko agba ile iwe na


Iyalenu ati kayefi nla lo je fun awon oluko ati akeko ile eko giga fasisti Ladoke Akintola Unifasiti nigbati awon ti won fura si lati je akeko ile eko giga na gbe ebo kankan si enu ona Oluko agba Prof. A.A Akingbade.

Iwadi nla tin lo lori oro na, won si ti pinu lati mu awon odaran ti won fi iru aso na se oro. Adura wa ni wipe ki Olorun gba wa lowo gbogbo awon ti a so, ti won so wa. Amin.

Comments