Ijoba ipinle Edo loni wo ile itura ti gbogbo eyan mo si Kabaka, ile itura to wa ni agbegbe Ugbor-Amagba ni opopona Oredo ni ijoba ipinle na. Ile itura na, to je ti ogbeni Tony Adun ni eleso abo ilu ati awon wole-wole ti se ami si lara wipe o je ibudo ti won ko lai tona.
Ti won si ti fi ye awon alase ile ise na wipe, laipe, lai jina, awon o wa wo ibudo na.
Comments
Post a Comment