Ogbontarigi olorin Victor Abimbola Olaiya ti lo ibi agba n're


Ibanuje nla lo je nigba ti irohin iku ogbontarigi olorin Highlife eni ti gbogbo eyan mo si Victor Olaiya to wa leti. Iwadi fi han wipe nkan bi ago mokanla osan oni ojo kejila osu keji ni ogbontarigi olorin na je olorun ni ipe.

Ile iwosan LUTH ni ologbe na ku si, omo odun kandinladorun ni ologbe na ki olojo to de.
Adura wa ni wipe ki Olorun te ologbe na si afefe ire, ki eyin ti won fi sile si ma baje. Amin.

Comments