Omo egbe agbaboolu Super Eagles, Odion Ighalo ti se afihan aworan lati fi idi re mule wipe oun ti darapo pelu egbe agbaboolu Man-United
Leyin gbogbo atotonu ton lon lori wipe se looto ni abi iro ni omo egbe agbaboolu Super Eagles Odion Igahlo ti darapo pelu egbe agbaboolu Manchester United, ni odomodekunrin na ti se afihan aworan pelu aso egbe agbaboolu na.
Eyi waye lati je ki gbogbo awon ololufe re mo wipe lai si ani-ani, looto ni oun ti darapo pelu egbe agbaboolu na.
Ninu iforowanilenuwo ti odomode kunrin na ba awon akorohin se, o fi da gbogbo awon ololufe re ati awon ololufe egbe agbaboolu Manchester United loju wipe didun ni osan o so nigba ti oun ti de egbe agbaboolu na, wipe oun o si fakoyo pelu ifokanbale.
Comments
Post a Comment