Ajo ton mojuto isesi awon Dokita ni orilede Nigeria (Nigerian Medical Association) ti pase fun won lati pada senu ise


Latari aisan ajakale arun COVID-19 to ti wo orilede Nigeria, ajo ton mojuto itoju ati ise awon Dokita ni orilede yi ti pase fun awon Dokita ti won gun le iyanselodi lati pada senu ise ni kia-kia. 

Ninu atejade ti adari egbe na Dr Francis Adedayo Faduyile se ni ilu Abuja, o ro awon Dokita na lati ranti oun ti bura lati se gege bi oniwosan oyinbo. O si fi won lokan bale wipe ijoba o se oun to ye ki won se ni kia-kia.

Atejade na ni yi ni ede geesi;

''We direct all medical associations that have declared industrial actions against their management to suspend all actions as the National NMA shall take over the dispute and interact with the different organs and agencies of the government. In this regard, the Association of Resident Doctors in the Federal Capital Territory, Kaduna and also in Gombe state as well as NMA in Cross Rivers state are to report back to work and treat Nigerians''







Comments