Awon molebi gbajugbaja olorin Kenny Rogers loni ojo kokanlelogun osu keta ti se atejade kan lati fi han wipe agbalagba olorin na ti ku.
Omo odun mokanlelogorin ni ologbe na ki olojo to de. Won fi han ninu atejade na wipe nkan bi ago mewa abo aro ni ologbe na dagbere faye.
Won so siwaju si wipe eto isinku na yo lo ni gbonkele latari ajakale arun Covid-19 to gbaye kan.
Adura wa ni wipe ki olorun te ologbe na si afefe ire. Amin.
Comments
Post a Comment