'Ogbeni Elon Musk, dakun sanu wa, a nilo iboju' Ajo ton mojuto eto oro aje orilede Nigeria lo ke gbajari



Ogbeni Elon Musk eni to je ikan lara awon oludasile ile ise Tesla loni se atejade kan lori ero ayelujara twitter wipe awon ti setan lati pin iboju kakiri gbogbo agbaye lati tako itankale arun COVID-19 to gbode kan.

Nigbara ti ajo ton mojuto ero oro aje orilede Nigeria ri atejade na lori ero ayelujara twitter, ni won ya tete ke gbajari wipe ki arakunrin na jowo sanu wa lorilede yi, nitoripe a nilo awon iboju na.

Oro yi lo ti wa di oun ti gbogbo awon omo orilede Nigeria n gba bi eni gba igba oti. Kini eyin ri si oro na?

Comments