Ajo ton soju egbe awon osise ni orilede Nigeria, NLC ti setan lati gun le iyanse lodi lati ola, ojo kejidinlogun osu kesan.
Iyanselodi na waye latari ai bikita ijoba si oro igbesiaye awon osise to wa ni orilede yi. Awon adari ajo na si ti pinu lati tesiwaju titi ijoba apapo o fi gbo oun ti won fe.
Comments
Post a Comment