Awon afurasi agbebon kan ni awon eleso abo ilu ti mu latari yinyinbo pa awon osise FRSC meji ni ipinle Nasarawa. Isele na sele nigba ti awon agbebon na doju ibon ko awon oko ayokele ton ko awon osise FRSC na lo, ti won yin ibon pa meji ninu won, ti won si ko awon iyoku lo ni igbekun.
Agbenuso fun ajo na, Bisi Kazeem eni to fi idi oro na mule na tesiwaju lati fi han wipe iwadi to peye tin lo lori oro na, lai pe owo o ba awon ajinigbe na.
Comments
Post a Comment