Awon agbebon kan yinbon pa odomodekunrin osise ile itura kan, ogbeni Falola Oke Olawuyi ni ilu Ilesa, ipinle Osun.
Awon ti oro na se oju won so wipe, awon agbebon na kolu odomodekunrin na ni nkan bi ago mesan-abo ale, ti won yinbon mo titi emi fi bo lenu re,
Awon agbofinro to wa ni ipinle na ti wa bere iwadi to peye lori oro na, won si fi ti so daju wipe lai pe, owo o ba awon odaran na.
Comments
Post a Comment