Ojo gbogbo ni tole, ojo kan ni ti olohun. Owo palaba arakunrin kan ton ji eran gbe segi ni ilu Abuja nigba ti awon ara adugbo gba mu ti won si lu ni alubami.
Isele na sele ni irole ana ni adugbo Abaji ni ilu Abuja. Igba ti owo iya ba arakunrin na lo jewo wipe lati ipinle Kogi ni oun ti ji arawon ewure na ko. Awon aradugbo na ti wa fa arakunrin na le awon agbofinro lowo.
Comments
Post a Comment