Àwon àwòrán níbi ayeye ojó ìbí Temídayò omobìrin Mo-Abudu

Odomodebirin Temidayo, eni to se ayeye ojo ibi ogbon odun ni awon ore, ibatan ati akegbe re wa ba se ajoyo ni ile re.

Odomodebirin na dupe lowo Olorun fun ore ofe lati wa laye ati ni alafia.





 

Comments