Godwin Obaseki ti wolé gégé bí Gomina ìpínlè Edo lábé egbé olósèlú PDP September 20, 2020 Get link Facebook X Pinterest Email Other Apps Awon omo ipinle Edo ti dibo yan Gomina Godwin Obaseki lati dari won gege bi gomina fun igba keji.Obaseki lo gbegba oroke pelu ibo 307, 955 to si na gbogbo awon akegbe re metala ti won jo figagbaga. Comments
Comments
Post a Comment