Ìjoba ìpínlè Abia ti pàse wípé kí àwon ilé èkó bèrè isé padà ní ojó-kejidinlogbon osù yí


 Latari wipe opin ti deba ajakale arun Covid19 ton ja ran-ran kakiri orilede ati ni gbogbo agbaye lapapo, Ijoba ipinle Abia ti wa pase fun awon ile eko lati pada senu ise won ki won si bere sini ko awon omo ni iwe pada bi o ti se wa tele.

Ikede na wa lati enu agbenuso fun Gomina John Okiyi-Kalu wipe ki ise bere pada. O wa so siwaju si wipe ki awon oluko ati adari ile eko kookan, ri wipe gbogbo awon nkan ti awon osise eleto ilera ti gbe kanle fun won lati woyaja pelu arun yi ni ki won maa lo.  

Comments