Ìjoba ìpínlè Òsun tín gbìyànjú láti yo Oba Ìlú Ìwó, Emperor Telu Abdulrasheed Àkànbí kúrò gégé bí Oba


 Ijoba ipinle Osun labe idari Gomina Gboyega Oyetola ti bere igbiyanju lati yo Oba Ilu Iwo Abdulrasheed Akanbi kuro gege bi Oba ilu na, nitori awon iwa ti ko boju mu fun Oba ilu lati wu, ti Oba na nwu. 

Won fi esun jagidi-jagan, asoju oro, ipata, ipanle, iwa odaran, ati ai bikita fun asa ati isese kan  Oba na. Waayi, awon oloye ilu na ti wa ko atejise, won si ti kora won jo lati koju igbiyanju ijoba Ipinle Osun na lati yo Oba na.



Comments