Igbeyawo laarin gbajugbaja olorin takasufe Cardi B ati oko re Offset fi fori sanpon. Ninu atejade kan ti olorin-birin na se lori ero ayelujara instagram, o fi han wipe ohun ti setan lati jawe fun odomodekunrin na, ki olukaluku si ma gbe ni alafia.
Awon ololufe mejeji na lo se igbeyawo ni odun 2017 ti Olorun si fi omobirin kan jinki igbeyawo na. Ile ejo Fulton County fi idi oro na mule.
Comments
Post a Comment