Ilu Zazzau to wa ni ipinle Kaduna ti se idaro Oba won,
Alhaji (Dr.) Shehu Idris. Iwadi fi ye wa wipe ile iwosan awon omo ologun ni Oba na ti papoda.Omo odun mẹ́rìnlélọ́gọ́rin ni Oba na ki olojo to de. Adura wa ni wipe ki Olorun te ologbe na si afefe ire amin.
Comments
Post a Comment