Idije Bigbrother Naija ti wa si ipari loni, ti Ogbeni Laycon ikan ninu awon oludije ninu idije na si gbegba oroke ninu idije na.
Opolopo atotonu lo ti wa lori eni ti yo gbegba oroke na nigba ti idi na sese bere, ikan ninu awon ti awon eyan foju si lara pupo julo ni arabirin Dorathy ati ogbeni Kidwaya latari ipa ribi-ribi ti won ko ninu idije na.
Sugbon awon ololufe ogbeni Laycon fi ye gbogbo eniyan wipe looto ni wipe awon fierce.
Won fierce gan!
ReplyDelete