Ògbóntarìgì òsèrébìrin Patience Ozokwor sukún ayò nígbà tí àwon omo rè fi okò ayókélé da lólá

Idunu ati ayo ni oserebirin Patience Ozokwor fi bomi loju nigba ti awon omo re fi oko ayokele Banz da lola ni ojo ibi re.

O dupe gidigidi lowo won, o si gba adura fun won.







 

Comments