Ibanuje nla lo je nigba ti irohin iku ogbontarigi osere ati oluko agba ni ile iwe giga Unifasiti Ilorin, arakunrin Ayobami Akinwale to wa leti.
Gege bi atejade ti awon molebi ologbe na se, won fi ye wa wipe ologbe na lo jade laye ni ale ojo ketala osu kesan odun 2020 leyin aisan ranpe. Omo ati omo-omo lo gbe yin ologbe na.
Adura wa si ni wipe ki Olorun te ologbe na si afefe ire. Amin
Comments
Post a Comment