Ija ti be sile lori ero ayelujara twitter larin awon omoge meji kan latari wipe ikan ninu won fi esun kan ikeji re wipe o ba orekunrin ohun gbajugbaja osere Timini Egbuson ni ajosepo.
Odomodebirin kan ti oruko re nje Toju na lo kegbajari to si kilo fun arabirin Lydia wipe ko so ara re, ki o ma ba kabuku oniyo. O so siwaju si wipe Timini ki se oko enikan, wipe oko gbogbo won ni.
Wayi, opolopo awon omidan miran lo ti wa tuyaya jade wipe gbogbo awon lawon jo ni oserekunrin na papa julo awon omidan ton gbe ni ilu Eko.
Comments
Post a Comment