Àwòrán níbi ayeye ìgbèyawo larin gbajúgbajà olórin Eriga àti olólùfé rè Moréniké

Ilu moka ati gbajugbaja odomodekunrin Olorin, Eriga, ninu atejade ati afihan awon aworan kan to se lori ero ayelujara instagram fi idunu re han lati gbe ololufe re olojo pipe Morenike ni iyawo.

O dupe lowo Olorun, o si kan sara si iyawo re fun gbogbo ife, atileyin ati ifarada.




 

Comments