Ogbeide Tijani, ìkan Pàtàkì lára àwon èsó gbajúgbajà olórin Davido ti kú

Ibanuje nla lo je nigba ti irohin iku ogeni Tijani ikan ninu awon eso gbajugbaja odomodekunrin olorin takasufe Davido jade. Gege bi iwadi ati awon atejade lori ero ayelujara, won fi han wipe ologbe na jade laye ni aro kutu-kutu oni leyin aisan ranpe.

Adura wa ni wipe ki Olorun fi orun ke ologbe na ki o si toju iyawo ati awon omo ti ologbe na fi sile lo. Amin.




 

Comments