Olorì Sílèkùnolá gbé àrèmo lo kí Ooni Adéyeyè Ògúnwùsì láàfin

Ooni Adeyeye Ogunwusi loni se afihan awon aworan nibi ayeye ikomo wole Aremo re tuntun Tadenikowo Adesoji Aderemi Eri-Ifeoluwasimi. O fi idunu re han, o si dupe lowo Olorun ati lowo ololufe re, Olori Wuraola Adeyeye Ogunwusi. 


 

Comments