Okere tan awon agbofinro meji lo ti so emi won nu ninu ikolu ti awon janduku kan se si ago olopa Zone 13 to wa ni Ukpo ni ipinle Anambra.
Nigba ti oga olopa ago olopa na Nkiru Nwode ba awon akorohin soro, o fi idi re mule wipe looto ni ikolu na waye, ti awon si mu awon janduku na ki won to sa lo.
Comments
Post a Comment