Ile ejo agba kan ni ipinle Zaria ti so arabirin osise ile ile iwe giga Ahmadu Bello University (ABU), Zaria arabirin Ebong Joy Akpan ati omobirin Inyene Akpan re si ewon osu mefa ati odun meje.
Awon mejeji lo pawo po fi esun kan awon akegbe re Muhammad Gimba Alfa, Mohammed Inusa, Lawal Yakubu Hunkuyi, Haruna Mohammed, Salisu Isa ati Rev. J. F Bukkah wipe nise niwon dijo gbimo po lati ji ohun gbe.
Latari eyi, adajo agba Abdullahi G. Maigamo so awon mejeji si ewon fun esun itanije and pipuromoni takoni.
Comments
Post a Comment