Gbajugbaja Ojise Olorun ati Ajihinrere Desmond Tutu ti ku


 Ajihinrere ati ojise Olorun, lati orilede South Africa, Desmond  Tutu ti ku. Ojise Olorun na, eni to se kutu-kutu meje ati yaya mefa nipa didekun ija eleya-meya to waye ni orilede South Africa ni o jade laye ni oni, ojo kerindinlogbon osu kejila, odun 2021.

Adorun odun ni ologbe na pe ki olojo to de.

Comments