Eto isinku oludije fun ipo Aare nigbakanri Bashir Tofa eni to je olorun ni ipe leyin aisan ranpe lo waye loni ojo keta osu kini odun 2022 gege bi isinku ni ilana musulumi.
Awon eyan jankan-jankan bi Imamu agba Shehu Tijjani Yan Mota, Emir ti ilu Kano, Alhaji Aminu Ado Bayero, Senito, Malam Ibrahim Shekarau, Minista fun eto ogbin, Alhaji Sabo Nanono, Alhaji Sule Yahya Hammai, Alhaji Aminu Dabo, Alhaji Sani Kwangila Yakasai ati Barr. A.B Mahmud lo peju sibi eto isinku na.
Comments
Post a Comment