Egbe agbaboolu Arsenal tun ti fi odun titun bere iya, nigba ti egbe agbaboolu Man City na won ni omi ayo meji si ookan

 

Iko egbe agbaboolu Manchester City tun ti fi iya da egbe agba boolu Arsenal lara ya lojo kini lodun titun. 

Boti le je wipe Bukayo Saka omo egbe agbaboolu Arsenal lo koko gba omi ayo kan wole ni isesebere idije na, eleyi ko dekun iya ti egbe agbaboolu Mancity ti ni lokan lati fi je iko egbe agbaboolu Arsenal.

Riyad Mahrez ati Rodri lo gba omi ayo mejeji na wole fun egbe agbaboolu Mancity.

Comments