Egbe agbaboolu Super Eagles ti de orilede Cameroon fun ipalemo idije AFCON


 Awon omo egbe ati oludari egbe agbaboolu Super Eagles loni ti de ilu Garoua ni orilede Cameroon fun ipalemo idije  Africa Cup of Nations, AFCON ton bo lona.

Nigba ti won ba awon oniroyin soro, won fi ipinu won lati gbe igba oroke nibi idije na, pelu gbogbo igbaradi ti won ti se.


Comments