Egbe agbaboolu Super Eagles ti fi agba han egbe agbaboolu Egipiti ninu idije ifesewonse AFCON


 Idije ifesewonse to waye laarin egbe agbaboolu Super Eagles ati awon akegbe won lati orilede Egipiti lo ti pari, ti iko egbe agbaboolu Super Eagles si fi agba han Egipiti nigba ti won na won ni omi ayo kan si odo. 1-0.

Omo egbe agbaboolu Super Eagles Kelechi Eanacho lo gba omi ayo kan na wole eleyi ti egbe agbaboolu Egipiti o ri ona lati da pada ti idije ifesanwonse na fi pari.

Comments