Ninu ifagagbaga- ifesewonse to waye laarin iko egbe agbaboolu Super Eagles ati akegbe won lati orilede Tunisia ninu idije AFCON ton lo lowo ni orilede Cameroon ni egbe agbaboolu Tunisa ti juwe ile fun awon egbe agbaboolu Super Eagles.
Omi ayo kan pere ni won gba wole, to si di isoro fun iko egbe agbaboolu Super Eagles lati da pada. Wayi, egbe agbaboolu Super Eagles ti ko eru won ti won si ti setan lati ma pada bo ni ilu awon ozu lati wa ma bo kaadi.
Comments
Post a Comment