Igbakeji Gomina ati Gomina ipinle Oyo nigba kan ri, Adebayo Alao Akala ni Irohin fi to wa leti wipe o ti je Olorun ni ipe ni idaji oni ojo kejila osu kini odun 2022 ni ilu Ogbomosho.
Irohin iku na je eyi to bani lokan je, sugbon gbogbo eniyan lo ti da agbada iku. Omo odun mokanleladorin ni ologbe na ki olojo to de.
Comments
Post a Comment