O tun ti Ze, ewa bami yo, mo ti ko ile tuntun ; Davido lo so be


 Gbajugbaja odomodekunrin olorin, ninu atejade kan to se lori ero ayelujara twitter, fi idunu re han, o si dupe lowo olorun fun oreofe ile tuntun ti o sese ko si Banana Island ni ipinle Eko.

Awa na ba olore yo.

Comments