O ma se o, odomodekunrin olorin Slim Joe ti ku

Ilu moka, odomodekunrin olorin Slim Joe ti ku, iwadi je ko ye wa wipe odomodekunrin na tin ba aisan kidirin ja fun bi odun melo kan seyin.

Ana, ojo keji osu kini odun yi ni odomodekunrin olorin na fi aye sile, omo ogbon odun ni ologbe na ki olojo to de.
 

Comments