Olubadan ti ilu Ibadan ti waja


Oba Saliu Akanmu Adetunji, Olubadan ti ilu Ibadan ti papoda. Odun metaleladorun ni oba na lo laye ki olojo to de. 

Adura wa ni wipe ki ile ati ona ti won fi sile ma baje.

Comments