Ewo awon omo Nigeria ton toro owo ni Sudan








Awon omo yi ni won ri lori titi Sudan ti won toro owo..Nigba ti won fi oro wa won lenu wo ni awon omo yi jewo wipe Katsina ati kano ni awon ti wa.......Nigeria Jagajaga

Comments