Ijamba oko kan sele loju ona Ibadan si Osun ni opopona Asejire
Get link
Facebook
X
Pinterest
Email
Other Apps
Ijamba ina sele nigba ti Oko ajagbe ton gbe epo ati oko akero kan fi ori so ara won ni opopona Asejire ni ona Ibadan si Osun...A o ti le so iye awon ti won fi ara pa abi awon ti won so emi won nu.
Comments
Post a Comment