Ana to je ojo aiku, 26th March, 2017, je ojo ayo ati idunu fun ojise olorun, ati alase ati oludari ijo Omega Fire Ministries worldwide, Apostle (Prof.) Johnson Suleman ni tori ijo na ni ayeye ojo ibi re.
lati dupe lowo olorun ati lati fi imore re han si awon omo ijo re, Pastor Sulaiman fun awon omo ijo re ni owo ati opolopo oko ayokele. O jo, o yo, osi dupe lowo olorun.



Comments
Post a Comment