Awon eleso abo di arakunrin kan to fe gba emi ara re lori 3rd Mainland Bridge lowo


Ni aro kutukutu oni ni awon osise eleso abo ilu di arakunrin yi lowo nibi to ti fe gba emi ara re ni ori 3d mainland bridge ni ilu eko. Nigba ti won bi wipe ki lo sele, o so wipe ile aye ti su ohun ni.

Comments